Sale!

ÀDÚRÀ IFẸ OLUWA SI MI

250.00 200.00

Mo ti ṣiwaju aṣiwaju wọ inu aiyé, ni orukọ Jesu, mo ti gbẹhin òṣìkà ti o fi igbéraga sọrọ̀ òdì si mi, ikú mi kò si lọwọ òṣìkà ènìyàn, Jesu ṣe ìdájọ́ mí o dámiláre…

Bi mo ba jẹ ẹgún ti mo jẹ Esusu, bi mo ba ti mu ẹjẹ Jesu, kò le pa mi lara, Oluwa fẹ mi ju bẹ lọ…

Agba ti wọn kora wọn jọ ni aginju si Mose, wọn kò mu ori dele, teniyan tẹranko lo parun ni aiyé ọjọsi, Noa nikan lo ku pẹlu idile rẹ, ọmọ Aaroni ti o kú sinu Agọ Mose, o ni bo ti jẹ, ẹmi ti o ba gbabọde ninu ile yi, ki o parun lojiiji…

Ilẹkun ile túbu ṣi, gbogbo ipilẹ mi titi laarin ọganjọ nitori ẹniti o ba ni Jesu ni Oludena yio ṣi ilẹkun fun, Oludena mo fẹ kọja lọ si ibi ire mi wa… NOTE: You will need to download an E-book reader on your mobile device before you can access the book.

Category:

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “ÀDÚRÀ IFẸ OLUWA SI MI”

Your email address will not be published. Required fields are marked *