Sale!

ÀDÚRÀ AWÚRE ONIGBAGBỌ

550.00 300.00

Ikú to fẹ ya Lasaru kúrò lara Jesu yóò wọ igbo lọ, kò ni dẹhin bọ, ọ̀rọ ti o ṣẹ ni iboji Jesu, bi kò ba ṣe oju angẹli yóò ṣe oju Oluṣọ, o jẹ dandan, ire mi yóò ṣe oju ọ̀tá mi lọdún yi…

Ohùn ẹniti ń kigbe ni iju, bi kò ba ṣe ọmọ Maria yóo ṣe ọmọ Elisabẹti, bi o ba ri bẹẹ, ki igbe alaafia máa dun ni ilé mi…

Abokúsọ̀rọ̀ kan kò ni ri Samuẹli ki o máa ta kìjì, ará Benjamini lo ni iya, ija àgba meji, Jakọbu ati angẹli, súre fún mi, mo ri kẹkẹ, mo ri agbada, kẹkẹ lọ, agbada ya mọ mi lọ́wọ́, Eliṣa kò pofo lẹhin Elijah, ń kò ni pofo lọdún yi…

Esau ti Rebeka tà ibukún rẹ fún Jakọbu, oun náà lo di ajitannawo lọjọ́ ìsìnkú Rebeka, ni oju aronipin ki Oluwa gbe ọ ga…

Iyẹ afẹfẹ ẹnikan kì í ri, ọ̀na Olodumare ẹnikan kò mọ. Afẹfẹ ń fẹ, ẹnikan kò mọ idi rẹ, oorun ń ran, ẹnikan kò mọ idi rẹ, o daju, okun ọla mi ayé kò ni mọ ọ láti ja…

Categories: , ,

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “ÀDÚRÀ AWÚRE ONIGBAGBỌ”

Your email address will not be published. Required fields are marked *